AWON AGBAAGBAA NIGERIA ATI ILE YORUBA TI BA OLA AWON ODO ILE YORUBA JE!!

#babagbagedeimo #koikimedia #omoluka #tennyomoologo #babagbagedelive #yeyedaratalk2 #awikonkoakandaoro #aarealmoroof #trend #trending #mrmacaroni

Check Also

FOOTBALL MANIA Hosted by MC LIVELY ||NASTY BLAQ||REMOTE||NASBOI|SAMSPEEDY||BRAINJOTTER||BAE U||

16 Content creators compete for a great price in Football Mania de Gossy. Organized by …

31 comments

  1. Yoruba Nation is under curse because of greed ati self-centredness. Educated illitrates and the so called useless elders that are so selfish and held us in bondage. The other useless thing about us Yorubas is the spirit of fears tio o ba je bee aa Ile Yoruba ma da bi Japan ni! Emi igberaga ati atenuje ko je kia gbadun! Let us wake up b4 it is too late!

  2. E se gaan ni pe e ni eto fun awon odo wa nitoripe awon ni ojo ola wa. Mo gba ladura pe Oluwa a fun yin se lagbara Olorun.

  3. Ibukun ni fun orile ede Yoruba lagbara Oluwa.

  4. Coordinate oyinbo niyens ki ise Yoruba. Kimi itumo coordinate in Yoruba

  5. Baba gbagede imo,Eku ise atotonu gbogbo igba,ise yin ti nyo diedie, olorun amu yin saseyori o Amin

  6. Seri.awon.tihape.ni.asaju.yi.tiobatije.omo.won.tabi.molebi.won.ati.imotara.eni.nikan.ounlodawon.lamun.gbogbo.ountioje.ina.ni.ile.tiwon.gbogbo.igba.ina.wani.ile.tiwon.ni.gbogbo.igba.oro.lesoeparo.leyikapin.ounlona.aboyo.loko.eru.awon.fulani.hausa.ati.awon.ojelu.awa.yoruba.yina.gbogbo.wonikaniwon.kelomo.

  7. What plans are on ground to implement many of the programs projected for the Youth in Yorubaland that is still part of Nigeria? I see so much hopelessness in Nigeria and not only for the Youth. So sad for a Nation God blessed with so much wealth

  8. Anango ni won so wipe a njé teletele.

  9. Baba gbagede, e seun gidi gan lopolopo,a mo looree o.🙏

  10. Ējòwó sir,EMI ngbo wipe Yoruba ko ni oruko Orilede wa,wipe aeon arewa ni won so wa ni Yorubawa ti itumo re sije onimonafiki ti a si tun le peni alabosi, bawo ni eleyi se jeebe?

  11. Once there is an unthentic database where everyone has registered to as omo Yoruba getting away with crime & fraud will be very difficult

  12. Eku eto olotu
    Adura mi ni wipe
    Ki olorun ran awon Agbeteru
    Ile yoruba nation lowo ki
    Won se aseyori
    Yoruba nation lole se
    Ki awon alale ti wa leyin
    Ki ase aseyori

  13. Ni italo na italo ma so fun yin wipe MiO GBo opolopo italo Lo Lo GBo ede oyin bo sugban italo ma so wipe MiO GBo ooo

  14. Won si oyin bo sugban won ma so fun yin wipe awon ogbo oyin bo

  15. Ẹku isẹ ẹyin bàbá mi eyin iya mi ẹgbọn mi lori imu orilẹ èdè wa duro ati fún òmìnira ile wa

  16. EDE Yoruba ni Oma poju EDE oyin bo Lo ju ti ama ma so ooo

  17. Yoruba nation no going back . Ti a spa Yoruba nation awon gbogbo Yoruba to wa ni diaspora awa le wa dase si le gbogbo awon Omo wa .arise. Okan wa bale, ekuise takutaku ti ense, e se de bi erę. Amin. Yoruba nation no going back.

  18. Yoruba nation ni Kan na ni ONAN Abayo ti ooo Le da gbogbo nkan ba Yi duro

  19. Ti Nigeria ba ni Eto bi ilu oyin bo ni Koni si Eni Kan to ma RO nu ogun Owo ooo

  20. Ti Ori Lede ba da ni gbogbo radarada Yi ooo Le mo SE Len

  21. Ori Lede ti ko da Lo fa gbogbo wahla Yi fun gbogbo Ile Yoruba patapata

  22. SE ti pa ti pa ni ki AFI WA papo ni aogbo EDE Ara WA ni Nigeria Hausa IGbo Yoruba Ako GBo ede Ara ki Oni kaluku lo lototo Yoruba nation no going back

  23. Aaaaaaaaaa OGA ooo won Kan NFI one Nigeria da ile Yoruba pada si eyan ni ooo

  24. In Nigeria everything is built on deceit

  25. ESE ooo sir Yoruba nation ni ONAN Abayo fun gbogbo Ile Yoruba patapata ooo

  26. Ekale sir ooo eku eto sir ooo eku ise takun takun sir ooo emiyin yio gun ni agbara olorun Ele du ma re oba oke tebi ti ara yin na ooo Yoruba nation no going back

  27. This are the things are governors in south west are supposed to be doing but their selfish interest is what they’re driving at how can a country exist without knowing the number of citizens they have

  28. EKU ISE TAKUNTAKUN LAGBARA OLORUN TODAWA SI ORILEEDE YORUBA YIO GBA ILE WA FUNWA

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *